EWAOLUWA – “MIMO” ft BBO | Download Mp3

Music 1 year ago

Download EWAOLUWA – “MIMO” ft BBO

USA-based Nigerian music minister, songwriter, and worshiper, Ewaoluwa Ayoola releases her debut single titled “MIMO” featuring BBO.

Download and listen up below!

Awon ti won yin Olorin nigbgbo igba won joko won duro niwaju ite re ko sohun ti won se

won yin won ke mimo si atobiju si atofarati bi oke

moni mo nso ti awon ti o wo aso funfun ti ogun ti olopin

won ki Oba ti olafiwe

won ki eniwaju ti nsiwaju ogun

won ki eni eyin ti nkeyin ogun

won ki eni nla ti n komo ye loju ogun

awon ti o jade ninu iponju ti wonsi so won di funfun ninu eje odo agatuan

won nbe niwaju ite olorun won si eniti ojoko lori ite ton siji bowon ebi ole pawon beni oungbe ole gbe won

won korin titun ka niwaju ite na ati niwaju awon eda alaye merin ati awon agbagba merinlelogun o

kosi eni ti ole mo orin na afi awon oke meje ole egbaaji eniyan eniyan ti ati rapada ninu aye

motun so ti angeli to fo lagbedemeji orun

mojuba eniti o da orun ataye okun ati gbogbo orisun omi

mo nko mimo si eni ti ote iyn isreali do

Olorun to gun kuku leshin

Olorun o ega fio fio eo lafiwe be leo lakawe

ina ti njo ni papa ti igbe orun oke to ga ju oke lo o

modarapo mo awon ti orun

awon ti won ko mimo o won se mimo

mimo lawon torun ke o awon to woso fun fun togun tion lopin

wonke mimi wonko mimi

mimo mimo lawon torun ke

awon ogun orun mimo wonke mimo si eledumare

awon ogun orun mmimo won ke mimo si onite ogo

awon ogun orun mimo wonke mimo si eledumare

mo bawon ko mimo mimo si Oba ogo

BBO

Si eni mimo to nse mimo to wu iwa mimo o

tawon agbagba merinlelogun nko mimo mimo si lojojumo eru re nba mi o

emi tokoja imisi omo eniyan ipa tobori gbogbo

ipa eda patapata bi ose wa ni gbara to

ofi agbara re ni aye lara o eru re mba mi o e

eyin lalasepe ayin lalasegbe eyin ni olorun to nse to muje oo

gbogbo agbara laye ati orun inu ikawo re lowa o

olorun odanikan sejoba bose wa je eni mimo to otun fi aye sile o fun oni doti to fe sunmo o felese to fe mo e

se kin maparo olori aye olgun ajoobo o eru re nba mi ooo ee

awon ogun orun mimo wonke mimo si eledumare

awon ogun orun mmimo won ke mimo si onite ogo

awon ogun orun mimo wonke mimo si eledumare

mo bawon ko mimo mimo si Oba ogo

mimo re oba ogo mimo re oba eda mimo re oba ogo

ogo oo mimo re oba ogo (2ce)

If you did not see a download button, kindly turn off "your ad-blocker" / "Data Savings" or try a different Browser like "Firefox Browser". After turning it off, reload page.
GODZILLA 262.32Mb
What's your rating?
0
{{ratingsCount}} Votes


Related Music
Ewaoluwa Ayobola – Oloja Ire
Music | 1 month ago

Ewaoluwa Ayobola – Oloja Ire

Ewaoluwa Ayoola - Agbara
Music | 10 months ago

Ewaoluwa Ayoola - Agbara

Tope Alabi – Mimo L’OluwaOba Ara
Music | 1 year ago

Tope Alabi – Mimo L’OluwaOba Ara

Ewaoluwa Ayoola -  Iranlowo Alaileniyan
Music | 1 year ago

Ewaoluwa Ayoola - Iranlowo Alaileniyan